ÃŒkÃni à ti èbè |
A kú ìmúra ONDÓ 2017.Bí a ti n múra ìpàdé ONDÓ 2017 e jé kí á gbàdúra kí a si se àyèwò ètò ìlera wa dáadáa.Ki a máse gbàgbé Àsùnwon àpò ìlera wa bí a ba ti n di erù wa.Olórun á dúró tì wá o.E máa fi àdúrà ràn wá lówó o.E seun .Olóyè Olábísi aya Aládéwòlú . |