E kú ojúmó ire owó,omo,ayó àti àlàáfíà.Àlàáfíà wa yóò máa pò si o.E jé kí a lo àwon ohun tí Elédàá fi ké wa fún ìlera wa. Òtútù àti òfìnkìn..... Èröjà:Àjó funfun(jínjà),Àlùbósà Gàmbàrí/Ááyù),Gún un pò kí o re é pèlú omi osàn wéwé sínú ike gbooro olómo orí. Léyìn ojó kejì bèrè sí lò ó. Lílò:Síbí ìjeun kan sínú ife omi gbígbóná kan.láàárò àti alé |