Ìpàdé Àpérò Kogí 2019 |
Aye̩ye̩ Àjò̩dún Àádó̩ta O̩dún (Júbílì) E̩gbé̩ Akó̩mo̩lédè àti Às̩à Yorùbá Nàìjíríà àti Ìpàdé Àpérò Gbogboogbò – Kogí 2019 tí ó wáyé ní Federal Government Girls College, Kàbbà, Ìpínlè̩ Kogí O̩jó̩ kìíní Ìs̩íde 05/08/2019 Ààre̩ E̩gbé̩ Akómo̩lédè O̩mó̩wùmí Aya Fálé̩ye̩ Díákónì wo̩lé sí gbò̩ngàn Ìpàdé Ìwúre Ìṣíde láti ẹnu Olóyè Diípọ̀ Gbénró (Ààrẹ Ìjẹta) Ọ̀rọ̀ àkọ́sọ Ààrẹ Díákónì Ọmọ́wùmí aya Fálẹ́yẹ Kábìyèsí O̩baje̩mu Ibinaye fi Máyégún E̩gbé̩ Akó̩mo̩lédè Je̩ Ijó Ìkíni káàbo̩ Ìpínlè̩ Kogí ní alé̩ o̩jó̩ Ajé Eré Ìbílè̩ Às̩álé̩ Ìpìnlè̩ Èkìtì 2
O̩jó̩ Kejì (06/08/2019) Ìdánilé̩kò̩ó̩ àti Eré Ìbílè̩ Às̩álé̩ Àwo̩n Ìpìnlè̩ |